Chris Ngige

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Chris Nwabueze Ngige
Aṣojú àárín Anambra ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà
Lórí àga
Ọjọ́ Ọ̀kàndínlọ́gbọ̀n Oṣù karún Odún 2003 – Ọjọ́ kẹtàdínlógún Oṣù kẹta Odún 2006
Asíwájú Chinwoke Mbadinuju
Arọ́pò Peter Obi
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́
Ìbí Ọjọ́ kẹjọ Oṣù kẹjọ Ọdún 1952
Ẹgbẹ́ olóṣèlú All Progressives Congress, APC.

Christian Nwabueze Ngige (bíi ní Ọjọ́ kẹjọ Oṣù kẹjọ Ọdún 1952) jẹ́ gómìnà Ipinle Anambra, Nàìjíríà láti Ọjọ́ Ọ̀kàndínlọ́gbọ̀n Oṣù karún Odún 2003 di Ọjọ́ kẹtàdínlógún Oṣù kẹta Odún 2006 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[1] Wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú àárín Anambra ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà ní Oṣù kẹrin Ọdún 2011 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress, APC.[2]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]