Aloysius Akpan Etok

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Aloysius Akpan Etok
aṣojú àríwá-ìwọ oòrùn Ìpínlẹ̀ Ibom State ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà
In office
2007–2015
Constituency Àríwá-ìwọ oòrùn Ìpínlẹ̀ Ibom State
Personal details
Ọjọ́ìbí 15 Oṣù Kejì 1958 (1958-02-15) (ọmọ ọdún 62)
Ẹgbẹ́ olóṣèlu People's Democratic Party (PDP)
Profession olóṣèlú àti olùkànsí

Aloysius Akpan Etok jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú àríwá-ìwọ oòrùn Ìpínlẹ̀ Ibom State ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin láti Ọdún 2007 sí Ọdún 2015 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[1][2]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Senator Etok's Biography". Senator Aloysius Etok. Retrieved 2009-09-22. 
  2. "A/Ibom, Rivers in Fresh Battle over NDDC’s Top Position". BusinessWorld. 2 July 2009. Retrieved 2009-09-22.