Philips Tanimu Aduda

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Philips Tanimu Aduda
Aṣojú Abuja ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà
Lọ́wọ́
Ó bọ́ sí orí àga
2011 sí 2015
Asíwájú Adamu Sidi Ali
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́
Ìbí Karu, FCT Abuja, Nigeria
Ẹgbẹ́ olóṣèlú People's Democratic Party (PDP)

Philips Tanimu Aduda jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú Abuja, ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà.[1] Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin láti Ọdún 2011 sí Ọdún 2015 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[2]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]