Jump to content

Gbenga Bareehu Ashafa

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Gbenga Bareehu Ashafa

Gbenga Bareehu Ashafa je oloselu ara Naijiria ati omo Ilé Alàgbà Nàìjíríà.( Ọjọ́ ìbí rẹ ọjọ́ keji lélógún, oṣù keje ọdún 1955 ). Ó jé asoju ilé ìgbìmò asofin àgbà fún ìlà oòrùn ìlú Èkó.