James Manager

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
James Manager
Alága ẹ̀ka People's Democratic Party ti ìpị́nlẹ̀ Delta
Lórí àga
ọdún 1998 – ọdún 1999
Arọ́pò Pius Sinebe
Aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà
Lọ́wọ́
Ó bọ́ sí orí àga
ọdún 2007
Constituency Gúúsù Delta
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́
Ìbí Oṣù Keje 1960 (ọmọ ọdún 57)
Ẹgbẹ́ olóṣèlú People's Democratic Party (PDP)
Profession Olóṣèlú


James Manager jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú Gúúsù Ìpínlẹ̀ Delta ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà láti ọdún 2003 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[1][2][3]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]