Adamu Gumba

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Sen Adamu Gumba
Aṣojú Gúúsù Bauchi ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
Ọjọ́ kẹtàlélógún Oṣù kẹjọ Ọdún 23 2010
AsíwájúBala Mohammed
Arọ́pòSen Ali Wakili
ConstituencyGúúsù Bauchi
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí10 Oṣù Kẹ̀wá 1948 (1948-10-10) (ọmọ ọdún 75)
Ọmọorílẹ̀-èdèỌmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeople's Democratic Party (PDP)
ProfessionOlóṣèlú

Adamu Gumba jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú Gúúsù Ìpínlẹ̀ Bauchi ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lẹ́yìn tí ó wọlé látàrí ètò ìdìbò ti oṣù kẹrin ọdún 2011 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[1]

Ó jẹ́ olórí àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba ti Bauchi.[2]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "SEN.GUMBA ADAMU IBRAHIM". National Assembly. Retrieved 2011-05-05. 
  2. "2011: Woman activist solicits support for women aspirants". Daily Triumph. July 20, 2010. Archived from the original on 2016-03-03. Retrieved 2011-05-05.