Bala Mohammed
Ìrísí
Bala Abdulkadir Mohammed | |
---|---|
Aṣojú Gúúsù Ìpínlẹ̀ Bauchi ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà | |
In office Ọjọ́ ọ̀kàndínlọ́gbọ̀ Oṣù karún Ọdún 2007 – Ọjọ́ kẹjọ Oṣù kẹrin Ọdún 2010 | |
Asíwájú | Abubakar Maikafi |
Arọ́pò | Adamu Gumba |
Mínísítà fún Àbújá | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga Ọjọ́ kẹjọ Oṣù kẹrin Ọdún 2010 | |
Asíwájú | Adamu Aliero |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 5 Oṣù Kẹ̀wá 1958 Alkedim tàbí Alakaleri, Bauchi State |
Bala Mohammed jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú Gúúsù Ìpínlẹ̀ Bauchi ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lẹ́yìn tí ó wọlé látàrí ètò ìdìbò ti oṣù kẹrin ọdún 2007 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[1]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Turaki A. Hassan (21 March 2010). "Yuguda behind my recall move – Sen Moh’d". media Daily Trust. Retrieved 2011-10-13.