Uche Chukwumerije

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Uche Chukwumerije
Aṣojú àríwá Abia ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà
In office
Ọjọ́ ọ̀kàndínlọ́gbọ̀n Oṣù karún Ọdún 2003 – Ọjọ́ ọ̀kàndínlógún Oṣù kẹrin Ọdún 2015
AsíwájúIke Nwachukwu
Arọ́pòTBD
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbíOṣù kọkànlá ọdún 1939
ìpínlẹ̀ Abia, Nàìjíríà
Aláìsí2015
Abuja, Nigeria
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPDP

Uche Chukwumerije (Oṣù kọkànlá Ọdún 1939 sí Ọjọ́ Ọkàndínlógún Oṣù kẹrin Ọdún 2015) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú àríwá Abia, ìpínlẹ̀ Abia ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin láti Oṣù kẹrin Ọdún 2011 sí Oṣù kejìlá Ọdún 2015 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[1]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. ORJI UZOR KALU (10 April 2011). "Orji Kalu Fails; Abaribe, Chukwumerije, Nwaogu Reelected Senators". Online Nigeria. Archived from the original on 2011-07-28. Retrieved 2011-04-20.