Emmanuel Nnamdi Uba

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Emmanuel Nnamdi Uba
Aṣojú Gúúsù Ìpínlẹ̀ Anambra ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
Oṣù karún ọdún 2011
AsíwájúIkechukwu Obiorah
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí14 Oṣù Kejìlá 1958 (1958-12-14) (ọmọ ọdún 65)
Enugu, Enugu State, Nigeria
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeople's Democratic Party (PDP)

Emmanuel Nnamdi Uba jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú Gúúsù Ìpínlẹ̀ Anambra ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà.[1] Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lẹ́yìn tí ó wọlé látàrí ètò ìdìbò ti oṣù kẹrin ọdún 2011 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]