Ahmed Hassan Barata
Ìrísí
Ahmed Hassan Barata | |
---|---|
Aṣojú Guyuk/Shelleng, Ìpínlẹ̀ Adamawa ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin kékeré | |
In office Oṣù karún Ọdún 1999 – Oṣù karún Ọdún 2003 | |
Aṣojú Gúúsù Adamawa ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga Oṣù karún Ọdún 2011 | |
Asíwájú | Grace Folashade Bent |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party (PDP) |
Ahmed Hassan Barata jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú Gúúsù Adamawa ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin láti Ọdún 2011 sí Ọdún 2015 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[1]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Collated Senate results". INEC. Archived from the original on 2011-04-19. Retrieved 2011-05-06.