Victor Ndoma-Egba

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Victor Ndoma-Egba
Aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà
Lọ́wọ́
Ó bọ́ sí orí àga
Odún 2003
Constituency Àárín Cross River
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́
Ìbí 8 Oṣù Kẹta 1956 (1956-03-08) (ọmọ ọdún 61)
Ẹgbẹ́ olóṣèlú People's Democratic Party (PDP)
Profession Amòfin àti olóṣèlú

Victor Ndoma-Egba (bíi ní ọjọ́ kẹjọ oṣù kẹta ọdún 1956) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà láti ọdún 2003.[1]

Ìpinlẹ̀ṣẹ̀ ayé rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Victor Ndoma-Egba ní ọjọ́ kẹjọ oṣù kẹta ọdún 1956 ní ilù Ikom, Ìpínlẹ̀ Cross River. Ó gba ìwé ẹ̀rí àkọ́kọ́ nínú ìmọ̀ òfin láti University of Lagos. Wọ́n pèé sí àwùjọ amòfin gẹ́gẹ́ bí agbẹjọ́rò ní ọdún 1978 tí ó si di Senior Advocate of Nigeria (SAN) ní ọdún 2004.[2] Ó ti fi ìgbàkan jẹ́ alága Nigerian Bar Association ti ẹ̀ka Calabar.

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]