Heineken Lokpobiri

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Heineken Lokpobiri
Aṣojú Ìwọ̀ oòrùn Balyesa ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà
Lọ́wọ́
Ó bọ́ sí orí àga
Oṣù kẹrin Ọdún 2007
Constituency Ìwọ̀ oòrùn Bayelsa
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́
Ìbí Ọjọ́ kẹta Oṣù Kẹta Ọdún 1967
Ẹgbẹ́ olóṣèlú People's Democratic Party (PDP)
Occupation Amòfin àti Olóṣèlú

Heineken Lokpobiri jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú Ìwọ̀ oòrùn Balyesa ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lẹ́yìn tí ó wọlé látàrí ètò ìdìbò ti oṣù kẹrin ọdún 2007 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[1][2][3]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]