Clever Ikisikpo
Appearance
Clever Marcus Ikisikpo | |
---|---|
Aṣojú Ìlà oòrùn Balyesa ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà | |
In office Oṣù karún Ọdún 2011 – Oṣù karún Ọdún 2015 | |
Asíwájú | Nimi Barigha-Amange |
Arọ́pò | Ben Murray-Bruce |
Constituency | Ìlà Oòrùn Bayelsa |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party (PDP) |
Clever Ikisikpo jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú Ìlà oòrùn Balyesa ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lẹ́yìn tí ó wọlé látàrí ètò ìdìbò ti oṣù kẹrin ọdún 2011 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[1]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "BAYELSA – HON. CLEVER M. IKISIKPO – PDP". Speaker's Office, Federal House of Representatives. Archived from the original on 2010-07-16. Retrieved 2011-04-22.