Ben Murray-Bruce
Ìrísí
Ben Murray-Bruce | |
---|---|
aṣojú Ìlà Oòrùn Balyesa ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga Oṣù Kàrún 29, 2015 | |
Asíwájú | Clever Ikisikpo |
Constituency | Ìlà oòrùn Balyesa |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 17 Oṣù Kejì 1956 Ìlú Èkó |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | PDP |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Evelyn Murray-Bruce |
Education | St. Gregory's College, Lagos |
Alma mater | University of South Carolina |
Occupation | Olóṣèlú, àti onị́ṣòwò |
Known for | Silverbird Group |
Website | benbruce.org benmurraybruce.com |
Ben Murray-Bruce jẹ́ oníṣòwò,[1] olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú Ìlà Oòrùn Balyesa ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lẹ́yìn tí ó wọlé látàrí ètò ìdìbò ti oṣù kẹrin ọdún 2011 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party. Ó jẹ́ olùdásílẹ̀ Silverbird Group.[2][3]
Àwọn ẹ̀bùn àti ẹ̀yẹ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- "Showbiz Icon of the Year Award" (2005)
- "“Top Ten” Significant Nigerian Businessmen Award" (2006)
- "Life Achiever Award" (2006)
- "Champion for Nation Building Award" (2007)
- "Excellent Personality Award" (2009)
- "Officer of Order of the Niger|the Order of the Niger" (2014)[4]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Florence Amagiya (27 December 2014). "A peep into Ben Bruce business empire". Vanguard Nigeria. Retrieved 2015-06-17.
- ↑ Richard Osunde (13 March 2013). "Ben Murray Bruce". Biography Home. Retrieved 2015-06-17.
- ↑ Emmanuel Aziken, Political Editor, Samuel Oyadongha & Henry Umoru (14 November 2011). "Bayelsa Guber ticket: PDP finally drops Sylva, Alaibe, Bruce". Vanguard Nigeria. Retrieved 2015-06-17.
- ↑ Richard Akinwumi (29 September 2014). "Jonathan names Nigeria’s national flag designer, Akinkunmi, special aide for life". Premium Times. Retrieved 2015-06-18.