Benedict Ayade

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Benedict Ayade
Ben-ayade-1.jpg
Ọ̀jọ̀gbọ́n Aṣòfin Ben Ayade
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Cross River
Lọ́wọ́
Ó bọ́ sí orí àga
Ọjọ́ ọ̀kàndínlọ́gbọ̀n oṣù karún ọdún 2015
Asíwájú Liyel Imoke
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́
Ìbí 2 Oṣù Kẹta 1969 (1969-03-02) (ọmọ ọdún 48)
Kakum, Obudu Ìpínlẹ̀ Cross River
Ọmọorílẹ̀-èdè Ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà
Ẹgbẹ́ olóṣèlú People's Democratic Party (PDP)

Benedict Ayade (bíi ní ọjọ́ kejì oṣù kẹta ọdún 1969) jẹ́ Gómìnà Ìpínlẹ̀ Cross River tí wọ́n dìbò yàn wọlé ní Ọjọ́ ọ̀kàndínlọ́gbọ̀n oṣù karún ọdún 2015, lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party, PDP.[1] Kí ó tó di gómìnà, ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà.[2]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]