Jump to content

Ahmed Abdul Ningi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Abdul Ahmed Ningi
Senato Abdul Ningi níbi ìpàdé ilé ìgbìmò asòfin àgbà
Igbákejì olórí àwọn tó pọ̀jùlọ ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
Ọjọ́ keje Oṣù kẹfà Ọdún 2011
ÀàrẹGoodluck Ebele Jonathan
AsíwájúMohammed A. Muhammed
Aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin kékeré
In office
Ọjọ́ kẹjọ Oṣù kẹfà Ọdún 1999 – Ọjọ́ kẹfà Oṣù kẹfà Ọdún 2011
AsíwájúWọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ da sílẹ̀
Arọ́pòAbdulrazaq Zaki
Chairman of the House Committee on Police Affairs
In office
Ọjọ́ kejìlá Oṣù kẹfà Ọdún 2007 – Ọjọ́ kẹfà Oṣù kẹfà Ọdún 2011
olórí àwọn tó pọ̀jùlọ ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà
In office
Ọjọ́ kẹwá Oṣù kẹfà Ọdún 2003 – Ọjọ́ kọkànlá Oṣù kẹfà Ọdún 2007
Alága tí House Committee fún àwọn ohun alùmọ́nì
In office
Ọjọ́ kọkànlá Oṣù kẹfà Ọdún 2002 – Ọjọ́ kẹsán Oṣù kẹfà Ọdún 2003
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Abdul Ahmed Ningi

20 Oṣù Kẹrin 1960 (1960-04-20) (ọmọ ọdún 64)
Ningi, Bauchi, Nigeria.
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeople's Democratic Party (PDP)
ResidenceNingi, Bauchi
Alma materAhmadu Bello University (BSc.)
ProfessionOṣìṣẹ́ ìjọba
WebsiteAbdulNingi.com

Ahmed Abdul Ningi jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú Àárín Ìpínlẹ̀ Bauchi ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lẹ́yìn tí ó wọlé látàrí ètò ìdìbò ti oṣù kẹrin ọdún 2011 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[1][2][3][4]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Abdul Ningi is majority leader". Nigerian Senate. 21 June 2011. http://www.nassnig.org/nass/index.php. 
  2. "2011 Elected Nigerian Senators". Nigeria Elections. 18 April 2011. Archived from the original on 13 April 2011. https://web.archive.org/web/20110413044448/http://nigeriaelections.org/nass.php. 
  3. JAMES OJO (5 August 2007). "Out of power, no one gives you any respect again". The Daily Sun. Retrieved 30 September 2009. 
  4. Aliyu Machika (23 June 2008). "Abdul Ningi Returns to the House". Daily Trust. Retrieved 30 September 2009.