Mohammed Ali Ndume
Appearance
Mohammed Ali Ndume | |
---|---|
Aṣojú Chibok ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin kékeré ti ilẹ̀ Nàìjíríà | |
In office Ọdún 2003 – 2011 | |
Aṣojú Gúúsù Borno State ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga Oṣù karú Ọdún 2011 | |
Asíwájú | Omar Hambagda |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party |
Mohammed Ali Ndume jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin kékeré ti ilẹ̀ Nàìjíríà lati ọdún 2003 sí 2011. Wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú Gúúsù Borno State ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà. Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lẹ́yìn tí ó wọlé látàrí ètò ìdìbò ti oṣù kẹrin ọdún 2011 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party, PDP.[1][2] [3]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ DAUDA MBAYA (31 December 2010). "Ndume Picks PDP Membership Card, Tackles ANPP". Leadership. Archived from the original on 2011-07-22. Retrieved 2011-05-04.
- ↑ Mustapha Isah Kwaru (9 January 2011). "Ndume’s defection and the fate of ANPP in Southern Borno". Peoples Daily. Retrieved 2011-05-04.
- ↑ "Collated Senate results". INEC. Archived from the original on 2011-04-19. Retrieved 2011-05-04.