Maina Maaji Lawan
Ìrísí
Maina Maaji Lawan | |
---|---|
House of Representative for Kukawa NE | |
In office Ọjọ́ kínín Oṣù kẹwá Ọdún 1979 – Ọjọ́ Ọkànlélọ́gbọ̀n Oṣù Kejìlá Ọdún 1983 | |
Governor of Borno State | |
In office Oṣù kínín Ọdún 1992 – Oṣù kọkànlá Ọdún 1993 | |
Asíwájú | Mohammed Marwa |
Arọ́pò | Ibrahim Dada |
National Senator for Borno North | |
In office Ọjọ́ Ọkàndínlọ́gbọ̀ Oṣù karún Ọdún 1999 – Ọjọ́ Ọkàndínlọ́gbọ̀ Oṣù karún Ọdún 2003 | |
Arọ́pò | Mohammed Daggash |
National Senator for Borno North | |
In office Ọjọ́ Ọkàndínlọ́gbọ̀ Oṣù karún Ọdún 2007 – Ọjọ́ Ọkàndínlọ́gbọ̀ Oṣù karún Ọdún2011 | |
National Senator for Borno North | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga Ọjọ́ Ọkàndínlọ́gbọ̀ Oṣù karún Ọdún 2011 | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Ọjọ́ kejìlá Oṣù keje Ọdún 1954 Kauwa |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | All Nigeria Peoples Party (ANPP) |
Alma mater | Ahmadu Bello University (ABU) |
Occupation | Oníṣòwò |
Profession | Olóṣèlú |
Website | Ojú òpó wẹ́ẹ̀bù rẹ̀ |
Maina Maaji Lawan jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó jẹ́ Gómìnà Ìpínlẹ̀ Borno tẹ́lẹ̀. Wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú àríwá Ìpínlẹ̀ Borno ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà.[1][2] Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lẹ́yìn tí ó wọlé látàrí ètò ìdìbò ti oṣù kẹrin ọdún 2011 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú All Nigeria Peoples Party ANPP.[3]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Sen. Maina Maaji Lawan". National Assembly of Nigeria. Archived from the original on 2008-12-22. Retrieved 2009-10-05.
- ↑ "An Improved Senate, But Some Uninspiring Senators...". This Day. 24 May 2009. Retrieved 2009-10-05.
- ↑ James Bwala (15 April 2011). "NASS election: Why Sheriff lost". Nigerian Tribune. Retrieved 2011-04-21.