Ahmed Zanna
Appearance
Ahmed Zanna | |
---|---|
Aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. | |
In office Oṣù karún ọdún 2011 – Ojọ́ Kẹrìndínlógún Oṣù karún Ọdún 2015 | |
Asíwájú | Kaka Mallam Yale |
Arọ́pò | TBD |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Ìpínlẹ̀ Borno, Nàìjíríà | 5 Oṣù Kínní 1955
Aláìsí | 16 May 2015 Abuja, Nàìjíríà | (ọmọ ọdún 60)
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | All Progressives Congress (APC) |
Ahmed Zanna (Ọjọ́ karún Oṣù kínín Ọdún 1955 – Ojọ́ Kẹrìndínlógún Oṣù karún Ọdún 2015) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú Àárín Ìpínlẹ̀ Borno ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà.[1] Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lẹ́yìn tí ó wọlé látàrí ètò ìdìbò ti oṣù kẹrin ọdún 2011 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[2]
Ó di olóògbé ní Ojọ́ Kẹrìndínlógún Oṣù karún Ọdún 2015.[3]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "CPC, ANPP demands cancellation of Borno Central senatorial election". Nigerian Compass. 24 April 2011. Retrieved 2011-04-25.
- ↑ "Borno senator-elect promises action on Lake Chad". Daily Triumph. April 15, 2011. Archived from the original on 2016-03-04. Retrieved 2011-04-25.
- ↑ http://www.ngrguardiannews.com/2015/05/borno-senator-ahmad-zanna-dies-at-60/