Barnabas Andyar Gemade

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Barnabas Andyar Iyorhyer Gemade
Aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin Nàìjíríà
Lọ́wọ́
Ó bọ́ sí orí àga
Oṣù karún ọdún 2011
Asíwájú Joseph Akaagerger
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́
Ìbí 4 Oṣù Kẹ̀sán 1948 (1948-09-04) (ọmọ ọdún 69)
Ìpínlẹ̀ Benue, Nàìjíríà
Ẹgbẹ́ olóṣèlú People's Democratic Party (PDP)

Barnabas Andyar Gemade jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú àríwá-ìwọorùn Ìpínlẹ̀ Bauchi ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà.[1] Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lẹ́yìn tí ó wọlé látàrí ètò ìdìbò ti oṣù kẹrin ọdún 2011 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[2][3][4]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]