Ita Enang

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Ita Solomon Enang
Ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà
Lórí àga
Oṣù karún ọdún 1999 – Oṣù karún ọdún 2011
Constituency Ibiono Ibom (Akwa Ibom)
Aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà
Lórí àga
Oṣù karún ọdún 2011 – Oṣù karún ọdún 2015
Asíwájú Effiong Dickson Bob
Constituency Àríwá-ìwọ oòrùn Akwa Ibom
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́
Ìbí 23 Oṣù Kẹjọ 1962 (1962-08-23) (ọmọ ọdún 55)
Ẹgbẹ́ olóṣèlú All Progressive Congress (APC)
Occupation Agbẹjọ́rò
Website http://www.itaenanglaw.com/

Ita Enang (bí ní ojọ́ kẹtàlélógún oṣù kẹjọ Ọdún 1962) jẹ́ olùrànlọ́wọ́ àgbà fún Ààrẹ Muhammadu Buhari lórí ọ̀rọ̀ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin. Ó jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú Itu àti Ibiono Ibom, Ìpínlẹ̀ Ibom State ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin kékeré ti ilẹ̀ Nàìjíríà lati ọdún 1999 sí 2011.[1][2] Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà láti Ọdún 2011 sí Ọdún 2015.[3]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]