Arthur Okowa Ifeanyi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Arthur Okowa Ifeanyi je oloselu ara Naijiria ati omo Ilé Alàgbà Nàìjíríà. Ni ọjọ 16th ọjọ kẹfa, ọdun 2022 ni Atiku Abubakar ti yan oludije fun ipo aarẹ ti Peoples Democratic Party gẹgẹ bi ẹlẹgbẹ rẹ fun idibo 2023.[1]Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]