Oluremi Tinubu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Oluremi Tinubu ( tí a bí ní ọjọ́ kọkàndínlógún, oṣù kẹsàn-án ọdún 1960) jẹ́ olóṣèlú ọmọ , bíbí Ìpínlẹ̀ Ògùn lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1] Ó jẹ́ Ìyàwó Bọ́lá Ahmed Tinúbú, ẹni tí ó jẹ́ Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó ní ọdún 1999 sí ọdún 2007. Rẹ̀mí tún jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ ilé-aṣòfin-Àgbà lowolowo (Senator) tí ó ń ṣojú fún Ẹkùn Àárín gbùngbùn Ìpínlẹ̀ Èkó,fún ìgbà Ìkẹ́ta ní Ilé Alàgbà Nàìjíríà.[2]

Ibèrè ayé àti èkó[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Olúrèmí Tinúbú jé àbíkéhìn nínú omo méjìlá; ó sì dàgbà ní ìpínlè Ogun State.

Olúrèmí ka èkó ilé-ìwé gíga ní University Ifè, àti Adeyemi College of Education.

Isé Olósèlú[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Olúrèmí Tinúbú je arabinrin àkókó tì'lu èkó nígbà ti oko re, Bólá Tinúbú, je gomina. Beeni o so da New Era Foundation, eyi to was fun idagbasoke ati igbega awon odo, ati lati kpolongo imototo awujo.


Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Themes, AccessPress (2019-08-12). "About Oluremi – Oluremi Tinubu @ Senate". Oluremi Tinubu @ Senate. Retrieved 2019-09-25. 
  2. "Oluremi Tinubu". Wikipedia. 2012-05-20. Retrieved 2019-09-25.