Enyinnaya Abaribe

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Enyinnaya Harcourt Abaribe
Aṣojú àríwá Abia ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
Ọjọ́ ọ̀kàndínlọ́gbọ̀ Oṣù karún Ọdún 2007
Asíwájú Adolphus Wabara
Igbá kejì Gómìnà Abia
Lórí àga
Ọjọ́ Ọ̀kàndínlọ́gbọ̀ Oṣù karún Ọdún 1999 – Ọjọ́ keje Oṣù kẹta Ọdún 2003
Gómìnà Orji Uzor Kalu
Personal details
Ọjọ́ìbí 1 Oṣù Kẹta 1955 (1955-03-01) (ọmọ ọdún 65)
Aba, ìpínlẹ̀ Abia , Nàìjíríà
Nationality ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà
Ẹgbẹ́ olóṣèlu PDP ( ANPP tẹ́lẹ̀)
Spouse(s) Florence Nwamaka (nee Morris)

Enyinnaya Abaribe (bíi ní Ọjọ́ kẹta Oṣù kẹta Ọdún 1955) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú Gúúsù Abia, ìpínlẹ̀ Abia ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin láti ọdún 2011 sí 2015 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[1]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. ORJI UZOR KALU (10 April 2011). "Orji Kalu Fails; Abaribe, Chukwumerije, Nwaogu Reelected Senators". Online Nigeria. Retrieved 2011-04-20.