Helen Esuene
Ìrísí
Helen Esuene | |
---|---|
Mínísítà Ìpínlẹ̀ Fún Ètò Ìlera | |
In office Oṣù keje Ọdún 2005 – Oṣù kínín Ọdún 2006 | |
Mínísítà Ìpínlẹ̀ Fún Ètò Àyíká | |
In office Oṣù kínín Ọdún 2006 – Oṣù kínín Ọdún 2007 | |
Asíwájú | Iyorchia Ayu |
Mínísítà Ìpínlẹ̀ Fún Ètò Àyíká àti Ilé | |
In office Oṣù kínín Ọdún 2007 – Oṣù karún Ọdún 2007 | |
Asíwájú | Rahman Mimiko (Ilé) |
Arọ́pò | Halima Tayo Alao |
Aṣojú Gúúsù Akwa Ibom ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà | |
In office Oṣù kẹrin Ọdún 2011 – Oṣù karún Ọdún 2015 | |
Asíwájú | Eme Ufot Ekaette |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Ojọ́ kẹtàlélógún Oṣù kọkànlá Ọdún 1949 |
Helen Esuene (bíi ní Oṣù kọkànlá Ọdún 1949) jẹ́ òṣìṣẹ́ ìjọba Nàìjíríà tẹ́lẹ̀ tí wọ́n yàn gẹ́gẹ́ bí mínísítà ìpínlẹ̀ fún ètò ìlera[1], tí wọ́n tún padà yàn gẹ́gẹ́ bíi mínísítà fún ètò àyíká àti ilé ní ìjọba Ààrẹ Olusegun Obasanjo láti ọdún 2005 sí 2007.[2] Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin láti Ọdún 2011 sí Ọdún 2015 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[3]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "As Obasanjo Reshuffles Cabinet... Ministers Under Probe for Corruption". BNW News. July 14, 2005. Archived from the original on 2012-01-11. Retrieved 2010-02-24.
- ↑ KABIRU YUSUF (January 11, 2007). "Obasanjo reshuffles cabinet...Swears-in 6 new ministers". Daily Triumph. Retrieved 2010-02-24.
- ↑ EMMANUEL CHIDIOGO (April 11, 2011). "PDP sweeps Akwa-Ibom". Daily Times. Retrieved 2011-04-21.