Goodluck Jonathan
Goodluck Jonathan | |
---|---|
President of Nigeria | |
In office 5 May 2010 – 29 May 2015 | |
Vice President | Namadi Sambo |
Asíwájú | Umaru Yar'Adua |
Arọ́pò | Muhammadu Buhari |
Vice President of Nigeria | |
In office 29 May 2007 – 5 May 2010 | |
Ààrẹ | Umaru Yar'Adua |
Asíwájú | Atiku Abubakar |
Arọ́pò | Namadi Sambo |
Governor of Bayelsa | |
In office 9 December 2005 – 29 May 2007 | |
Asíwájú | Diepreye Alamieyeseigha |
Arọ́pò | Timipre Sylva |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Goodluck Ebele Azikiwe Jonathan 20 Oṣù Kọkànlá 1957 Ogbia, Nigeria |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Patience Faka |
Alma mater | University of Port Harcourt |
Goodluck Jonathan [ọjọ́ìbí 20 Noveber (Belu)1957][1] jẹ́ olósèlú ọmọ ilè Nàíjíríà àti Àare orílé èdè Nàíjíríà láti May (Èbìbi) 6, 2010. Ohun ní igbákejì Àare ilè Nàíjíríà sí àare Umaru Músá YarAdua kí ó tó dibo fun gégé bí adìbó àare ni 9 February, 2010 nítorí aìsàn tó dé ba YarAdua mólè. Léyin ti Yar'Adua kú ní May (Èbìbi) 5, 2010, jónáthàn di [2] bakan yéyé ó tun jẹ gómìnà ìpínlè Bàyélsà larin 9 ọpẹ́(December) 2005 àti 28 Ebìbí (May) 2007 àti igbákejì Gòmìnà Ipinle [3]
Igbesi aye Ibẹrẹ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]G
Goodluck Jonathan ní a bi ni 20 Oṣu kọkanla ọdun 1957 ni Ilu Ogbia si idile Kristiani kan ti awọn ti n ṣe ọkọ-ọkọ, làti ẹya Ijaw to kere ni Ipinlẹ Bayelsa.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Lawson Heyford, "Jonathan: A Colossus at 49" Archived 2009-01-15 at the Wayback Machine., The Source (Lagos), 11 December 2006
- ↑ Jonathan, Goodluck Ebele (2021-05-12). "Goodluck Ebele Jonathan – ACCORD". ACCORD. Retrieved 2023-06-12.
- ↑ "Goodluck Jonathan - Biography & Facts". Encyclopedia Britannica. 2010-04-08. Retrieved 2023-06-12.
Wikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Goodluck Jonathan |