Salamatu Hussaini Suleiman
Salamatu Hussaini Suleiman | |
---|---|
Ecowas Commissioner for Political Affairs, Peace and Security | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga January 2012 | |
Minister of Women Affairs | |
In office December 2008 – March 2010 | |
Asíwájú | Saudatu Bungudu |
Arọ́pò | Josephine Anenih |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Argungu, Kebbi State, Nigeria |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Education | LLB, Ahmadu Bello University, Zaria, Master's degree in Law, London School of Economics and Political Science |
Profession | Lawyer |
Salamatu Hussaini Suleiman jẹ́ agbejọ́rọ̀ tí ó sì jẹ komísọ́nà lórí ọ̀rọ̀ òṣèlú, àlàáfíà àti àbò fún ẹgbẹ́ ECOWAS.[1] Ní oṣù kejìlá ọdún 2008, wọ́n fi jẹ mínísítà lórí ọ̀rọ̀ obìnrin àti ìdàgbàsókè ìlú.[2][3]
Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Salamatu Hussaini Suleiman sí ìlú Argungun ní ìpínlẹ̀ Kebbi. Bàbá rẹ̀ jẹ́ adájọ́, ìyá rẹ sí wá láti ìdílé ọba ní Gwada. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Queens College ni Èkó. Ó tẹ̀ síwájú sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Ahmadu Bello University ní ìpínlẹ̀ Zaria, ó sì gboyè nínú ìmò òfin.
Iṣẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ pẹ̀lú Ministry of Justice ní ìpínlẹ̀ Sókótó. Lẹ́hìnńà ó ṣiṣẹ́ pẹ̀lú ilé ìfowópámọ́ Continental Merchant Bank ní ìlú Èkó fún ọdún méje. Ó siṣẹ́ pẹ̀lú NAL Merchant Bank fún ìgbà díè kí ó tó lọ sí Ilé iṣẹ́ Aluminium Smelter Company níbi tí ó ń tí ṣe onímòràn òfin fún wọn. Ààrẹ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tẹ́lẹ̀, Umaru Yar'Adua fi Suleiman jẹ mínísítà lórí ọ̀rọ̀ àwọn obìnrin ní oṣù kejìlá ọdún 2008.[4][5]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ KPOGNON, Paul D. "CEDEAO". news.ecowas.int. Archived from the original on 2018-09-26. Retrieved 2017-12-20.
- ↑ LAMBERT TYEM (May 11, 2009). "I’m not a politician, but a technocrat –Salamatu Suleiman, Women Affairs Minister". Archived from the original on July 18, 2009. Retrieved 2009-12-26. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Daniel Idonor (17 March 2010). "Jonathan Sacks Ministers". Vanguard. Retrieved 2010-04-14.
- ↑ Anza Philips, Abuja Bureau (24 December 2008). "The Coming of New Helmsmen". Newswatch. Archived from the original on 2011-06-17. Retrieved 2009-12-26.
- ↑ Damilola Oyedele (16 September 2009). "Minister Decries Low Women Participation in Politics". This Day. Retrieved 2009-12-26.