Omoniyi Caleb Olubolade

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Omoniyi Caleb Olubolade
Alamojuto Ipnle Bayelsa
In office
27 June 1997 – 9 July 1998
AsíwájúHabu Daura
Arọ́pòPaul Obi
Alakoso awon Ojuse Pataki
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
6 April 2010
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí30 Oṣù Kọkànlá 1954 (1954-11-30) (ọmọ ọdún 69)
Ipoti-Ekiti, AII Ijero, Ipinle Ekiti, Nigeria

Omoniyi Caleb Olubolade (ojoibi 30 November 1954) je Navy Captain totifeyinti ni ibise ologun ojuomi orile-ede Naijiria ati Gomina Ipinle Bayelsa tele. O je yiyansipo Alakoso Ojuse Pataki ninu kabineti Aare Goodluck Jonathan ni 6 Osu Kerin, 2010.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]