Jump to content

Gregory Agboneni

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Gregory Agboneni
Administrator of Adamawa State
In office
9 December 1993 – 14 September 1994
AsíwájúAbubakar Saleh Michika
Arọ́pòMustapha Ismail
Administrator of Cross River State
In office
14 September 1994 – 22 August 1996
AsíwájúIbrahim Kefas
Arọ́pòUmar Farouk Ahmed

Gregory Agboneni je omo ologun ile Nigeria to tifeyinti ti o di Olumojuto Ologun fun Ipinle Adamawa ati Ipinle Cross River larin December 1993 ati August 1996 nigba ijoba ologun Ogagun Sani Abacha.[1]


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Nigerian States". WorldStatesmen. Retrieved 2010-01-01.