Jump to content

Dáníẹ́l Archibong

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Daniel Archibong)
Daniel Patrick Archibong
Àwòrán ti Patrick Dam Archibong
Gomina Ipinle Cross River
In office
January 1984  1986
AsíwájúDonald Etiebet
Arọ́pòEben Ibim Princewill
Àwọn àlàyé onítòhún
AláìsíMarch 11, 1990

Daniel Archibong je omo ologun nibi Ise Ologun ile Naijiria. Nigba ijoba ologun Ogagun Muhammadu Buhari o je yiyan sipo gege bi Gomina Ipinle Cross River lati 1984 de 1986.