Dáníẹ́l Archibong

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Daniel Patrick Archibong
Gomina Ipinle Cross River
Lórí àga
January 1984 – 1986
Asíwájú Donald Etiebet
Arọ́pò Eben Ibim Princewill
Personal details
Aláìsí March 11, 1990

Daniel Archibong je omo ologun nibi Ise Ologun ile Naijiria. Nigba ijoba ologun Ogagun Muhammadu Buhari o je yiyan sipo gege bi Gomina Ipinle Cross River lati 1984 de 1986.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]