Jump to content

Timipre Sylva

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Timipre Sylva
Governor of Bayelsa State
In office
29 May 2007  16 April 2008
AsíwájúGoodluck Jonathan
Arọ́pòWerinipre Seibarugo
Governor of Bayelsa State
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
27 May 2012
AsíwájúWerinipre Seibarugo

Timipre Sylva jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Olóṣèlú ni, ó sì ti fi ìgbà kan jẹ́ Gómìnà ni Ipinle Bayelsa. Ní ìgbà àkọ́kọ́ tí yóò jẹ gómìnà, ó g'orí òye ni ọjọ́ Kọkàndínlọ́gbọ̀n, oṣù karùn, ọdún 2007, ó sì fi ipò náà sí lẹ̀ ni ọjọ́ Kẹrìndínlógún, oṣù kẹrin ọdún 2012. Ṣáájú àkókò yìí, ó ti jẹ́ ọmọ ilé ìgbìmò aṣòfin ni ìpínlẹ̀ Rivers àná.

Ìbẹ̀rẹ̀ ìgbésí ayé

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]


A bí Timipre Sylva ní ọjọ́ keje, oṣù keje, ọdún 1964[1] ní agbègbè tí à ń pè ní Brass, ní ìpínlẹ̀ Bayelsa (eléyìí tí a ti ń fi ìgbà kan pè ní ìpínlẹ̀ Riverss.

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. http://bayelsa.gov.ng/government/executive/the-governor.html