Emmanuel Uduaghan
Appearance
Emmanuel Eweta Uduaghan | |
---|---|
Governor of Delta State | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 29 May 2007 | |
Asíwájú | James Ibori |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 22 October 1954 Warri North, Delta State, Nigeria |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party (PDP) |
Emmanuel Eweta Uduaghan (ojoibi 22 October 1954) ni Gomina Ipinle Delta lowolowo ni Nigeria lati May 29 2007, o je omo egbe oloselu People's Democratic Party (PDP). Ki o to di Gomina o je Asakoso fun Ilera ni Ipinle Delta ati Akowe fun Ijoba Ipinle Delta.[1]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "THE EXECUTIVE GOVERNOR". Delta State Government. Archived from the original on 2010-04-24. Retrieved 2009-12-29.