Ibikunle Amosun
Jump to navigation
Jump to search
Senator Ibikunle Amosun | |
---|---|
Alagba fun Ogun Central | |
In office May 29, 2003 – May 29, 2007 | |
Asíwájú | Femi Okurounmu |
Arọ́pò | Iyabo Obasanjo-Bello |
Alagba fun Ogun Central | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga May 29, 2019 | |
Asíwájú | Lanre Tejuoso |
Gomina Ipinle Ogun | |
In office May 29, 2011 – May 29, 2019 | |
Asíwájú | Gbenga Daniel |
Arọ́pò | Dapo Abiodun |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 25 Oṣù Kínní 1958 |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | All Progressives Congress (APC) |
Ibikunle Amosun (ojoibi 25 January 1958) je oloselu ara Naijiria ati gomina Ipinle Ogun lati ojo 29 osu Karun 2011 de 2019. Amosun je Alagba ni Ile Alagba Asofin Naijiria lati 2003 de 2007 ati lowolowo lati May 2019.
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
- ↑ "Monthly Environmental Sanitation Still Stands In Ogun State – Amosun". Channels Television. April 25, 2015. http://www.channelstv.com/2015/04/25/monthly-environmental-sanitation-still-stands-in-ogun-state-amosun/. Retrieved August 31, 2015.