Theodore Orji

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
His Excellency

Theodore Ahamefule Orji

CON
8th Gómìnà ìpínlẹ̀ Abia
In office
May 29, 2007 – May 29, 2015
AsíwájúOrji Uzor Kalu
Arọ́pòOkezie Ikpeazu
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí1950
Umuahia Ibeku Abia State, Nigeria
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeople's Democratic Party (PDP)

Theodore Ahamefule Orji jẹ́ olóṣèlú ará ilẹ̀ Nàìjíríà àti Gómìnà Ìpìnlẹ̀ Abia láti ọdún 2007 títí dé 2015. Ní ìgbàkan rí ó jẹ́ òṣìṣẹ́ ìjọba àti pé ó jẹ́ olórí àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba ní abẹ́ Gómìnà Orji Uzor Kalu.Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]