Aishatu Dahiru Ahmed
Sen Aishatu Dahiru Ahmed | |
---|---|
Senator | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 2019 | |
Asíwájú | Abdul-Aziz Nyako |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 11 Oṣù Kẹjọ 1971 |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | All Progressives Congress |
Other political affiliations | People's Democratic Party (formerly) |
Education | University of Southampton |
Profession | Politician
Engineer |
Aishatu Dahiru Ahmed (ojó ìbí rè ni 11 August 1971) ti a tun mo si Binani jẹ òkan lara àwon Sẹnatọ Nigeria labe egbe oselu All Progressives Congress(APC), o nsoju agbegbe Adamawa Central senatorial District [1] O jẹ ara awon ile igbimo asofin(House of Assembly) larin odun 2011-2015 lábé egbe oselu People's Democratic Party(PDP), o se asoju agbegbe Yola North,Yola South ati Girei Federal constituency. [2]
Àárò ayé rè
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A bi Aishatu sí ìlú Adamawa ní odun 1971, o sì lo ilé-ìwé government secondary ní Yola, léyìn náà, o lo sí Federal polytechnic ti ìlú Mubi, ìpínlè Adamawa. O lo sí Yunifásitì ti Southampton láti tèsíwájú ìwé rè.
Kí o to di pé o padà darapo mó oselu, o jé onisowo ati alaga Binani Nigeria limited Binwa Press Limited, Triangular Communications Ltd., Golden Crescent Nigeria Ltd., Infinity Telecoms Ltd. ati Quest Ventures [3]
Àwon Ìtókasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Women who will shape Ninth Senate". Vanguard News. 2019-03-04. Retrieved 2022-05-20.
- ↑ "Nigerian Newspaper, Breaking News, Politics, Business And More". Leadership News (in Èdè Bosnia). 2018-12-21. Retrieved 2022-05-20.
- ↑ "Aishatu Binani - Portail de l'Afrique de l'Ouest". West Africa Gateway. 2019-03-14. Archived from the original on 2021-10-18. Retrieved 2022-05-20.