Atiku Abubakar

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Atiku Abubakar
Atiku Abubakar.jpg
11th Vice President of Nigeria
In office
Oṣù Kàrún 29, 1999 – Oṣù Kàrún 29, 2007
ÀàrẹOlusegun Obasanjo
AsíwájúMike Akhigbe
Arọ́pòGoodluck Jonathan
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbíOṣù Kọkànlá 25, 1946 (1946-11-25) (ọmọ ọdún 75)
Adamawa State, Nigeria
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeople’s Democratic Party

Atiku Abubakar (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n oṣù kọkànlá ọdún 1946) jẹ́ gbajúgbajà olóṣèlú ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Adamawa lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Òun ni Igbákejì Ààrẹ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà nígbà ìṣèjọba Ààrẹ Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ́. [1][2] Lọ́dún 2019, ó díje dupó Ààrẹ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà lábẹ́ àsíyá ẹgbẹ́ òṣèlú People’s Democratic Party tako Ààrẹ Muhammadu Buhari tí ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress, ṣùgbọ́n ìbò àti orí kò ṣe é lóore, ó fìdí remi.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Atiku Abubakar - Profile". Africa Confidential. 2019-12-19. Retrieved 2019-12-19. 
  2. "The Nigerian operator who knows how to make money". BBC News. 2019-02-06. Retrieved 2019-12-19.