Annie Okonkwo
Annie Okonkwo je Alagba ni Ile Alagba Asofin Naijiria lati 2007 doni.
Clement Annie Okonkwo | |
---|---|
Senator for Anambra Central | |
In office 29 May 2007 – May 2011 | |
Asíwájú | Emmanuel Anosike |
Arọ́pò | Chris Ngige |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 23 Oṣù Kàrún 1960 Ojoto, Anambra State, Nigeria |
Clement Annie Okonkwo (ti a bí ni ojó ketalelogun oṣù kàrún ọdún 1960) ọ dibo ile asofin fun agbegbe aarin Anambra Anambra State, Nigeria, iṣẹ beere ni ojó kokandinlogbon osu karún ọdún 2007. Ọkàn lára ọmọ ẹgbẹ́ People's Democratic Party (PDP).[1]
Okonkwo ẹni tí a bí ni ojo ketalelogun oṣù kàrún ọdún 1960 ní Ojoto, l'ẹba Onitsha ni Anambra State.[2] O ka ìwé síwájú sí láti gbà diploma nínú ìsàkóso, Harvard University, USA (1997-1998), ìwé síwájú Diploma nínú oníṣòwò ofin ati ìwà, University of Lagos (1995-1997) pẹlu diploma síwájú sí nínú ìpolówó ọjà, University of Lagos (1994 - 1995).[1] Nínú ìṣòwò, o kò ilé iṣẹ nla ti ọ gbà egberun méje ènìyàn ní àwọn ilé iṣẹ Reliance Telecomm, Clemco Industries, Modern Communications (satellite TV Network), MacClemm Marketing Communications, Sunflower Nigeria and Pentagon Oil.[2]
Lẹyìn tí ọ gbà àga gẹgẹ bí olóṣèlú, a Yàn láti sójú ìgbìmò lori Upstream Petroleum Resources, ọrọ awọn ọlọpa, agbegbe (vice-chairman) ati ọgbin.[1] Nínú ayẹwo iṣẹ awọn olóṣèlú ni oṣù kàrún ọdún 2009, ThisDay se àpèjúwe okonkwo gẹgẹ bí ẹni tí ọ fi múlẹ láti jẹ kí ohun ọgbin àti oúnjẹ din owó fún ará ìlú àti awọn ara òke òkun ile Naijiria le ri ra .[3] Ni oṣù Kejì ọdún 2010 o di je Anambra State bí gomina.[4] sibẹsibẹ, o pa danu sí ọwọ gomina ti a Yàn , Peter Obi,[5]
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 1.2 "Sen. Annie Okonkwo". National Assembly of Nigeria. Archived from the original on 2016-03-03. Retrieved 2010-06-15. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ 2.0 2.1 "About Annie". Annie Okonkwo. Archived from the original on 14 June 2009. Retrieved 2010-06-15. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "An Improved Senate, But Some Uninspiring Senators...". ThisDay. 24 May 2009. Retrieved 2010-06-15.
- ↑ Charles Onyekamuo (30 August 2009). "Okonkwo Vs Obi - A Paradoxical Challenge". ThisDay. Retrieved 2010-06-15.
- ↑
"Obi Re-elected Anambra State Governor...(UPDATED)". ThisDay. 2 July 2010. Archived from the original on 12 February 2010. Retrieved 2010-02-07. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)