Jump to content

Musiliu Obanikoro

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Musiliu Obanikoro je agba oloselu omo bibi ilu Eko nile Yoruba lapa gusu iwo-oorun orile-ede Naijiria.[1] O ti figba kan je asofin-agba (Senator) ni odun 2003 si 2007 nibiti o ti soju ipinle Eko nile igbimo asofin-agba. Ni odun 2014, Aare-ana, Goodluck Jonathan yan-an gegebi Minister-kereje fun aabo orile-ede (Defense Minister Of state).[2]

Awon Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "About Obanikoro". Senator Obanikoro (in Èdè Ruwanda). Archived from the original on 2019-09-21. Retrieved 2019-09-21. 
  2. "Musiliu Obanikoro". Wikipedia. 2007-02-01. Retrieved 2019-09-21.