Jump to content

Badamasi Maccido

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Badamasi Maccido
Senator for Sokoto North
In office
May 2003 – October 2006
AsíwájúAliyu Abubakar
Arọ́pòAhmed Muhammad Maccido
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí1961
Sokoto State, Nigeria
Aláìsí29 October 2006

Badamasi Maccido (1961-2006) je Alagba ni Ile Alagba Asofin Naijiria lati 2003 de 2006 nigba to ku ninu ijanba baalu ADC Airlines Flight 53 pelu baba re Mohammadu Maccido ati omo re.