Oserheimen Osunbor
Ìrísí
Oserheimen Osunbor je oloselu ara ile Naijiria ati Alagba lati Edo ni Ile Igbimo Asofin lati 1999 titi de 2007. Ohun si lo tun ti je Gomina Ipinle Edo lati 2007 de 2008.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |