Lucky Igbinedion

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lucky Nosakhare Igbinedion
Governor of Edo State
In office
29 May 1999 – 29 May 2007
AsíwájúAnthony Onyearugbulem
Arọ́pòOserheimen Osunbor
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí13 May 1957
(Àwọn) olólùfẹ́Mrs Eki Igbinedion
Àwọn ọmọDr Mrs Ehi Oni (nee Igbinedion), Mr Nosa Igbinedion Jr, Mr Osaretin Igbinedion, Ms Osasu Igbinedion, Mrs Zena Enaholo (nee Igbinedion), Ms Aize Ibginedion
EducationMBA
Alma materJackson State University, Mississippi, US
Websitehttp://www.luckyigbinedion.co.za/

Lucky Nosakhare Igbinedion ni wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹtàlá oṣù Karùn ún, ọdún 1957, jẹ́ ọmọ bíbí àti gómìnà Ìpínlẹ̀ Ẹdó nígbà kan rí lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú PDP, ní ọdún 1999 sí ọdún 2007.[1].


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2018-07-24. Retrieved 2020-05-03.