Mohammed Abba Aji

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Isa Mohammed
Aṣojú àárín Niger ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà.
In office
Oṣù karún Ọdún 1999 – Oṣù karún Ọdún 2007
Arọ́pòZainab Abdulkadir Kure
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí1948
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeople's Democratic Party (PDP)

Mohammed Abba Aji jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú àárín Niger ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin láti Oṣù karún Ọdún 2011 sí Oṣù karún Ọdún 2015 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party..[1][2]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Tatalo Alamu (8/11/2009). "A rousing encounter with Senator Isa Mohammed". The Nation. Retrieved 2010-05-12.  Check date values in: |date= (help)
  2. Kola Ologbondiyan (22 October 2004). "Assault: the Road to Isa Mohammed's Suspension". ThisDay. Retrieved 2010-05-12.