Emeka Anyaoku

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí

Eleaza Chukwemeka Anyaoku

A bí i ní 18th January, 1932 ní ìpínlè Anambra ní ilè Nàìjíríà. Ó lo sí ile-èkó ní Merchant of Light School, Oba; University of Ibadan, Institute of Public Administration, London; Cavillam Institute, France. Ó ti se minister of foreign affairs rí. Ó sisé ní Foreign Service. Ó je Secretary Commonwealth.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]