Don McKinnon
Sir Donald McKinnon ONZ GCVO | |
---|---|
4th Commonwealth Secretary-General | |
In office 1 April 2000 – 1 April 2008 | |
Asíwájú | Emeka Anyaoku |
Arọ́pò | Kamalesh Sharma |
12th Deputy Prime Minister of New Zealand | |
In office 2 November 1990 – 16 December 1996 | |
Alákóso Àgbà | Jim Bolger |
Asíwájú | Helen Clark |
Arọ́pò | Winston Peters |
24th Minister of Foreign Affairs | |
In office 2 November 1990 – 5 December 1999 | |
Alákóso Àgbà | Jim Bolger (1990 - 1997) Jenny Shipley (1997 - 1999) |
Asíwájú | Mike Moore |
Arọ́pò | Phil Goff |
Member of Parliament for Albany | |
In office 1978–1993 | |
Asíwájú | Seat established |
Arọ́pò | Murray McCully |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 27 Oṣù Kejì 1939 London, Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | National |
Sir Donald Charles "Don" McKinnon, ONZ, GCVO (tí a bí ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n ọdún kejì, ọdún 1939) ni igbákejì alákoso àgbà àti alákòóso ọ̀rọ̀ òkèèrè nígbà kan rí fún orílẹ̀-èdè New Zealand. Òun tún ni Akowe Agba fún ẹgbẹ́ Ajoni awon Orile-ede láti ọdún 2000 títí di 2008.
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí McKinnon sí Blackheath, ní London. Bàbá rẹ̀ ni Walter McKinnon, tó jẹ́ olóyè fún àwọn òṣìṣẹ́ gbogboogbò, ó sì tún fìgbà kan jẹ́ ààrẹ New Zealand Broadcasting Corporation. Àwọn àbúrò rẹ̀ ní John McKinnon, àti Malcom McKinnon. Àwọn àbúrò rẹ̀ yìí jẹ́ bàbá-ńlá John Plimmer, tí àwọn èèyàn tún mọ̀ sí "father of Wellington".[1]
McKinnon kàwé gboyè ní ilé-ìwé Khandallah, ó sì tún lọ Nelson College láti ọdún 1952 wọ 1953.[2] Ní ọdún 1956, ó kékọ̀ọ́ gboyè ní ilé-ìwé Woodrow Wilson, ní Washington, D.C.[3] McKinnon tún lọ ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti Lincoln Agricultural college, ní New Zealand. Ó padà di olùdarí oko kan, ó tún wá padà dí ẹni tí àwọn ènìyàn ń bẹ̀ wò fún iṣẹ́ oko.
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Dominion Post 18 June 2009 page C2
- ↑ Nelson College Old Boys' Register, 1856–2006, 6th edition
- ↑ McKinnon, Don (2006-05-25), Building Sustainable Democracies – the Commonwealth way (PDF), Center for Strategic and International Studies[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]