Odumegwu Ojukwu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
General C. Odumegwu Ojukwu
President of Biafra
In office
30 May 1967 – 8 January 1970
Vice PresidentPhilip Effiong
AsíwájúPosition created
Arọ́pòPhilip Effiong
ConstituencyBiafra
Governor of Eastern Region, Nigeria
In office
19 January 1966 – 27 May 1967
AsíwájúFrancis Akanu Ibiam
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1933-11-04)4 Oṣù Kọkànlá 1933
Zungeru, Nigeria
Aláìsí26 November 2011(2011-11-26) (ọmọ ọdún 78)
United Kingdom
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúNigerian Military, Biafra military, later APGA
(Àwọn) olólùfẹ́Bianca Ojukwu
Alma materLincoln College, Oxford University
ProfessionSoldier, politician

Chukwuemeka Odumegwu-Ojukwu (a bíi ní ọjọ́ kẹrin oṣù kọkànlá ọdún 1933[1] - ó sì kú ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù kọkànlá ọdún 2001)jẹ́ ológun àti òsèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tẹ́lẹ̀ [2]. Ó fìgbà kan jẹ Gómìnà ológun apá àríwá Nàìjíríà lọ́dún 1966. Oun ló ṣe égbátẹrù ogun abẹ́lé Biafra fi tako ìjọba orile-ede Nàìjíríà lọ́dún 1967 sí 1970[3].

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Ojukwu's birthday". 
  2. "Ojukwu's death announced". Archived from the original on 2011-11-27. Retrieved 2011-11-26. 
  3. "Chukwuemeka Odumegwu Ojukwu Facts". Biography. 1967-05-30. Retrieved 2019-10-06.