Joseph Akahan

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Joseph Akahan
Ọ̀gá ológun ti orílẹ̀ èdè Nàìjíríà
Lórí àga
Oṣù karún ọdún 1967 – Oṣù karún ọdún 1968
Asíwájú Yakubu Gowon
Arọ́pò Hassan Katsina
Personal details
Ọjọ́ìbí Ọjọ́ kejìlá Oṣù karún ọdún 1937
Gboko LGA, Ipinle Benue, Nigeria
Aláìsí May 1968 (1968-06) (ọmọ ọdún 31)

Joseph Akahan (12 April 1937 - May 1968) jẹ́ ọ̀gá ológun ti orílẹ̀ èdè Nàìjíríà láti oṣù karún ọdún 1967 sí karún ọdún 1967, tí ó sì kú látàrí ìjàmbá ọkọ̀ òfúrufú tí ó wáyé nígbà ogun abẹ́lé Nàìjíríà.[1][2]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Chronicle of Command". The Nigerian Army. Retrieved 2010-06-01. 
  2. Dr. Nowa Omoigui. "BARRACKS: THE HISTORY BEHIND THOSE NAMES (PART 7 - EPILOGUE Section 1)". Dawodu. Retrieved 2010-06-01.