Binta Ayo Mogaji
Ìrísí
Bíńtà Ayọ̀ Mọ́gàjí | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 1964 |
Iṣẹ́ | Actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 1970s - present |
Gbajúmọ̀ fún | Igbáńládogí |
Olólùfẹ́ | Victor Ayọ̀délé Oduleye |
Àwọn ọmọ | 3 |
Bíńtà Ayọ̀ Mọ́gàjí ni wọ́n bí ní ọdún 1964 jẹ́ gbajúgbajà òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí ìlú Ìbàdàn ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ láti orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Gẹ́gẹ́ bí onímọ̀ sinimá àgbéléwò, Shaibu Husseini ṣe sọ, Bíńtà Ayọ̀ Mọ́gàjí tí kópa nínú sinimá àgbéléwò, eré-ìtàgé, àti eré àṣà fihàn orí tẹlifíṣàn tó ti tó ẹgbẹ̀rin (800).[1]
Ìgbà èwe rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Born Bíńtà Ayọ̀ Mọ́gàjí Lọ́dún 1964. Ó jẹ́ ọmọ bíbí Agbo ni ìlú Ìbàdàn ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ láti orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Bàbá jẹ́ Àlùfáà Mùsùlùmí, ìyá rẹ̀ sì jẹ́ olùkọ́ àgbà. Ayọ́ fẹ́ gbábọ́ọ̀lù-fẹ̀yìntì àti eléré ìdárayá, Victor Ayọ̀délé Odùlẹ́yẹ.[2] kí ó tó lọ́kọ, òun àti gbajúmọ̀ òṣèré mìíràn, Jíbọ́lá Dábọ̀ ń ṣeré ìfẹ́ tí wọ́n sìn bímọ kan fún ara wọn.[3][4]
Àtòjọ díẹ̀ nínú àwọn sinimá-àgbéléwò rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Kasanova (2019)
- Pasito Deinde (2005)
- Àkóbí Gómìnà 2 (2002)
- Eni Eleni 2 (2005)
- Nowhere to be Found
- Why Worry the Barber?
- Sergeant Okoro
- Igbáńládogí
- Mojèrè
- Owò Blow
- Ti Olúwa Nilẹ̀ (1992)[5]
- Motherhood
- Òwò Àlè
- Ìlẹ̀kẹ̀
- Ojuju
- Ilé Olórogún
- Checkmate
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Husseni, Shaibu (April 17, 2018). "Binta Ayo Mogaji: Sterling stage and screen actress Sambas on and off the turf". Guardian. Retrieved 2018-07-17.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "You were in school when i started receiving award--------Binta Ayo Mogaji-Oduleye". Modern Ghana. May 18, 2009. Retrieved 2018-07-18.
- ↑ "7 FACTS ABOUT BINTA AYO MOGAJI AS SHE CLOCKS 52". Playground. Archived from the original on 2018-10-22. Retrieved 2018-07-17.
- ↑ Inyese, Amaka. "Jibola Dabo was only my boyfriend, I’m married to a British Psychotherapist" says actress". Pulse. Retrieved 2018-07-17.
- ↑ "Now I have who’ll call me mummy’ (Actress Binta Ayo Mogaji in her 40s)". Nigeria Voice. December 19, 2004. Retrieved 2018-07-18.