Moji Afolayan
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Mojí Afọláyan)
Moji Afolayan | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Ibadan, Oyo, Nigeria | 5 Oṣù Kejì 1969
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ |
|
Olólùfẹ́ | Rasaq Olayiwola |
Parent(s) | Ade Love (father) |
Àwọn olùbátan | Kunle Afolayan (brother) Gabriel Afolayan (brother) Aremu Afolayan (brother) |
Moji Afolayan tí wọ́n bí ní Ọjọ́ karùn-ún oṣù kejì ọdún 1969 (February 5, 1969) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin, olóòtú àti olùdarí sinimá-àgbéléwò ọmọ bíbí Yorùbá láti ìlú Ìbàdàn lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1] Mojí jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ bíbí olóògbé òní-sinimá àgbéléwò Adeyemi Afolayan[2] tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Ade Love nígbà ayé rẹ̀. Moji Afolayan fẹ́ gbajúgbajà òṣèré sinimá àgbéléwò, Razaq Olayiwola tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Ojopagogo. [3]
Iṣẹ́ Fíìmù Rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní ọdún 2016, Afolayan tó ti ṣeré nínú ọ̀pọ̀ àwọn eré Nàìjíríà tí ó fi hàn pẹ̀lú Ojopagogo àti Dele Odule nínú eré fíìmù Yorùbá "Àrìnjó".
Ayé Rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ó ṣe ìyàwó sí Rasaq Olasunkanmi Olayiwola, òṣèré ọkùnrin ti ilẹ̀ Nàìjíríà tí gbogbo ayé mọ̀ sí orúkọ orí ìtàgé rẹ̀, "Ojopagogo".
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Why my husband stays at home to nurse the kids-Moji Afolayan". The Nation Newspaper. Retrieved 27 February 2015.
- ↑ "Dad didn’t encourage his children to act —Kunle Afolayan". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. 2015-02-28. Archived from the original on 2015-02-28. Retrieved 2019-12-31. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Latest Nigeria news update". The Nation Newspaper (in Èdè Latini). 2018-09-03. Retrieved 2019-12-31.