Toyin Afolayan

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Toyin Afolayan
Ọjọ́ìbí(1959-09-24)24 Oṣù Kẹ̀sán 1959
Orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Orúkọ mírànLola Idije
Iṣẹ́Osere Itage

Tóyìn Afoláyan (ọjọ́ìbí. ọjọ́ 24 osù kẹsàn-án, ọdún 1959) tí gbogbo ènìyán mọ̀ sí Lọlá Ìdíje jẹ́ òṣèré onítíátà Nàìjíríà lóbìnrin àti àntí fún òṣèré onítíátà Nàìjíríà lọ́kùnrin Kúnlé Afọláyan.[1] Ó di gbajúmọ̀ òṣèré lẹ́hìn tí ó kópa pàtàkì gẹ́gẹ́ bi Madam Àdìsá nínu fiimu 1995 kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Deadly Affair.[2]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]